About Us (Nípa Wa)
About Us
Bàtâ Magazine was founded out of a passion for the richness and beauty of Yoruba literature. We are an online literary magazine committed to the publication of Yoruba poetry; serving as a digital platform for both established and emerging poets.
One of our core beliefs is in the uniqueness of the Yoruba language, and an urgent need to preserve this cultural heritage for generations to come. Thus, we are committed to changing the narrative in the volume and accessibility of published Yoruba poetry.
Through our online platform and publication of chapbooks, we are building a collection of works that will celebrate the language, history and artistry of the Yoruba people.
We aim to expand our efforts someday into producing not just digital but also physical copies of our magazine and poetry collections, solidifying our commitment to the preservation of the Yoruba culture.
Nípa Wa
Ìpìlẹ̀ Bàtâ Magazine je ìfẹ́ íjinlẹ fún ẹwà lítíréṣọ̀ Yorùbá. A jẹ́ ìwé-ìròyìn orí ìńtánẹ́ẹ̀tì fún gbígbé ewì Yorùbá jáde àwọn akéwì tó ti fìdí múlẹ̀ àti àwọn tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ń bọ̀ wá sí ìtàn.
Ọ̀kan lára àwọn ìgbàgbọ́ pàtàkì wa ni pé èdè Yorùbá ṣe kókó láti gbé larugẹ fún ìdàgbàsókè àṣà ati iṣe wa; fún àwọn ìran tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú. Nítorí náà, a ti pinnu láti yí ìtàn pa dà nípa bí a ṣe ń tẹ àwọn ewì Yorùbá jáde ki ò lè rọrùn láti ri.
Nípasẹ̀ ẹrọ-ayélujára àti títẹ àwọn ìwé ewì kéékèèké jáde, a ń ṣàkójọ àwọn iṣẹ́ ewì tó ń fi ọlá fún èdè, ìtàn, àti ìṣẹ́ṣe àwọn Yorùbá.
A gbàgbọ́ pé lọ́jọ́ iwájú, a má láǹfààní láti tẹ́ ìwé ewí Yorùbá fún ìpamọ àṣà Yorùbá.