
Nígbà tí a bá bí omo wọ́n má kán oyin sẹ́nu rẹ̀, ṣùgbọ́n kò sí ẹni tó sọ fún un pé, ayé kì í dun títí, ati pé pípé jé ìrújú

Nígbà tí a bá bí omo wọ́n má kán oyin sẹ́nu rẹ̀, ṣùgbọ́n kò sí ẹni tó sọ fún un pé, ayé kì í dun títí, ati pé pípé jé ìrújú

Ìṣòro, bí wọ́n bá pè ọ ní Ayọ̀déle, àti pé ahọ́n wọn máa yọ̀ sórí fawelì bí okuta ìbòṣepọ̀. Ìṣòro, bí wọ́n bá dín án kù sí Ayọ̀

Mo tẹ̀síwájú pẹ̀lú yíyí afẹ́fẹ́, tí ń gbá erùpè Kúrò lójú ọ̀nà mi, láti ṣí ọ̀nà sí ìjọba àtijọ́ Ti àwọn baba ńlá mi. Mo wá láti bùkún

Kí ìyá mi tó bími Bàbá mi ti bí ìrètí Bàbá mi, Ìyá mi, pẹ̀lú ìrètí wọn ni wọ́n fi orúkọ fún mi bí a ti ń fún ọba ládé

Kòkòrò ni mí, n ò mọ ibi a kìí kọjú ijó sí. Gúdúgúdú ni mí, n ò mọ ibi a kìí fi ẹsẹ̀ ìlù sí Bí mo bá ń jó

Kókósẹ | ninú àlá yẹn òún gbé ike omi láti ẹ̀yìnkùlé níbití ìyá wa ti gbé pè ó ní ohùn òkè ó sì sáré gba

Wàhálà Púpọ̀ Nínú Orílẹ̀-Èdè Yìí | Wàhálà, bí o bá jẹ́ Olùwòran, tí o ń wo ìwọ́de láti òkèèrè pẹ̀lú ọwọ́ rẹ wà nínú àpò

Kí lódé tó fi dáhùn ní èdè Yorùbá | Tí mo bá bá ọ sọ̀rọ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì/ bí àwọn Òyìnbó ṣe ń ṣe é/ pẹ̀lú ahọ́n tí ó nípọn