
Anvil
Original Author
Adedayo Agarau
Translator
Alfred Olaiya
Date Published
Anvil
(Previously published in HAD)
in that dream,
you are carrying
a bucket of water
from the backyard
to the kitchen where
our mother called you
at the top of her voice
& as you rushed through
the small dark corridor
of the old brown house
we used to live in ogunleye
you slipped & fell & laid
there, silent in the way
language forsakes the
tongue; the ship of
your body unable
to turn itself
towards
shore.
Kókósẹ
ninú àlá yẹn
òún gbé
ike omi
láti ẹ̀yìnkùlé níbití
ìyá wa ti gbé pè ó
ní ohùn òkè
ó sì sáré gba
àárín ilé kékeré to dúdú
ti ilé àtijọ́ aláwọ̀ pípọ́n
ògúnlẹyẹ là n gbé nigbanà
o yọ́ o sì subú, o nara sílẹ̀
níbè, ìdákérọ́rọ́ lójú ọ̀nà
èdè ko
ahọ́n sìlẹ̀; ọkọ́ ojú omi
ara rẹ kùnà
láti yípadà
sí ọ̀nà
etí òkun.
Original Author
AA
Adedayo Agarau
Translator
AO